Download “You Are Worthy” by “Tope Alabi”

Lyrics

hmmmmm
ohhhhh
ehhhhhhh

You are worthy, you are worthy, you are worthy of my praise (2ce)

Eleburuike oooo
Oranmonisefayati oooo
Aranibanilo ooooo
You are worthy
Oba to gba mi la o
Olowo ina oooo
Iwo nikan logo ye ooo
You are worthy

You are worthy, you are worthy, you are worthy of my praise (2ce)

Lion of the tribe of Judea
Kinging in his majesty
Ruler of the universe
I tremble at your feet

Lion of the tribe of Judea
Kinging in his majesty
Ruler of the universe
Worthy of our worship

You are worthy, you are worthy, you are worthy of my praise (2ce)

Olola to ga ju lo
Oloro to poju lo
Ologo to ga ju you are worthy
Oba to ju gbogbo oba lo
Ijoba ni bi gbogbo olori aye
Isale ile
Alainipekun ni o.

You are worthy, you are worthy, you are worthy of my praise (2ce)

Oforun nikan se kiki da wura
Oda orun pelu aye pelu ara oto
Ebo mi aji to la
Mo gbo su ba fogo ra bale
Ibeere ogo arin ogo
Olunkangun igbeyin ogo
Eniti gbogbo aye yio
Pada wa bo
Kabiesi oooo

Araye koba ni kabiesi
Won ni kade pe lori ki
Bata pe lese o
Iwo nikan ni kabiesi
Ta o gbodo so pe kade pe lori fun
Ewo a o gbodo ni ki bata pe lese lailai
Sade ta o
Mo gba to gori e
Se bata ta o mo gba to wo ese re

Download Here
Please follow and like us:
0

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *